Main content
àééì jẹ́ ètò tí ò n ṣ'àgbéyẹ̀wò àwọn ǹkan ìyàlẹ́nu tí ó wà ní agbègbè wa tàbí tí àwọn ǹkan àrà tó ṣẹlẹ̀ nítòsí wa, paapàá jùlọ àwọn ǹkan tí ojú kò rírí tàbí àwọn ǹkan tí ó yàtọ̀ pátápátá sí àwọn ǹkan tí etí tí gbó rí. Kókó ètò náà ni láti tọ́ka sí àwọn ǹkan àrà wọ̀nyí, ibí tí wọ́n wà tàbí tí wọ́n ti ṣẹlẹ̀ kí á sì ṣàlàyé ǹkan tí ayé kò mọ̀ nípa wọn.